Owé

Ohun tí ojú ń wá ni ojú ń rí.

Ìtúmọ̀ rẹ̀ ni pé nígbà tí a wá nǹkan, a lè rí nǹkan náà. Nǹkan tí a fẹ́ rí ni ẹ máa rí. Nǹkan tí a fẹ́ mọ̀ ni a máa ń ṣe ìwádìí fún. Nǹkan tí a fẹ́ ṣe l’óòótọ́ ni a máa ń tiraka láti ṣe.