1. Ohun tí ìyá ní kí Dàpọ̀ ṣe tí ó fi ń bú ìyá rẹ̀ ni pé kí ó fọṣọ.
  2. Tọ́lá àti Kúnlé kọrin fún Dàpọ̀ nítorí pé ó hùwà tí kò dára.
  3.  Ohun tí yóò ṣẹlẹ̀ sí ẹni bá rí ìyá rẹ̀ fín ni pé yóò tòṣì.