Àwọn ọ̀rọ̀ tuntun pẹ̀lú àwọn àwòrán
Ìkòkò
Ibùsùn
Garawa
Kọ́kọ́rọ́
Ẹ̣̣̀rọ asọ̀rọ̀ mágbèsì
Ọ̀pọ̀lọ́
Àgùtàn
Adìẹ
Òdòdó
Afárá
Pèpéle
Àwọn ọ̀rọ̀ tuntun pẹ̀lú àwọn àwòrán
Ìkòkò
Ibùsùn
Garawa
Kọ́kọ́rọ́
Ẹ̣̣̀rọ asọ̀rọ̀ mágbèsì
Ọ̀pọ̀lọ́
Àgùtàn
Adìẹ
Òdòdó
Afárá
Pèpéle
Nàìjíríyà ni orílẹ̀-èdè t’ó wà ní ìhà ìwọ̀ oòrùn ilẹ̀ Adúláwọ̀. Àbújá ni olú-ìlú Nàìjíríyà. Èkó ni ìlú t’ó tóbi ju àwọn ìlú mìíràn t’ó wà ní Nàìjíríyà lọ. Àádọ́ta ọ̀kẹ́ ènìyàn gbé níbẹ̀. Yorùbá, Haúsá, àti Igbo ni èdè Adúláwọ̀ mẹ́ta nínú àwòn èdè púpọ̀ t’ó wà ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríyà. Àkàrà ni ọ̀kan nínú irú àwọn oúnjẹ tí àwọn ọmọ Nàìjíríyà sábà máa ń jẹ. A ní láti fi òróró dín ẹ̀wà lílọ pẹ̀lú àlùbọ́sà, ata àti iyọ̀ nínú. Ní Gánà, a máa ń pe àkàrà ní ‘koóse’. Méjì nínú àwọn orúkọ mi ni orúkọ Nàìjíríyà!
Ama Onyankopɔnbo Àjàgbẹ̀yàlà Diasizi Diasilwa Mpolo-Lunungu Ẹ̀sankìígbé Kambon