Category Archives: Yorùbá

Iṣẹ́ l’oògùn ìṣẹ́

Iṣẹ́ l’oògùn ìṣẹ́

Adwuma yɛ ohia  aduro

Iṣẹ́ l’oògùn ìṣ̣ẹ́, múra síṣẹ́ ọ̀rẹ́ mi, iṣẹ́ ni a fi ń dẹni gíga.

Adwuma yɛ ohia ano aduro, hyɛ wo sapɔ mu nsuo yɛ adwuma m’adamfo, adwuma na yɛde yɛ nnipa akɛseɛ.

Bí a kò bá rẹ́ni fẹ̀yìn tì, bí ọ̀lẹ là ń rí.

Sɛ yɛnni obi a yɛtumi dan no a, yɛte sɛ akwadwofoɔ.

Bí a kò bá rẹ́ni gbẹ́kẹ̀lé; a tẹra mọ́ iṣẹ́ ẹni.

Sɛ yɛnni obi a ɔbɛgyina yɛn akyi a, ɛwɔ sɛ yɛyɛ yɛn ankasa yɛn adwuma.

Ìyá rẹ lè l’ówó l’ọ́wọ́; ki bàbá rẹ sì l’ẹ́ṣin l’éèkàn

Wo na tumi nya sika bebree, w’agya tumi nya apɔnkɔ bebree.

                                                                                                                    

Bí o bá gbójú lé wọn, o tẹ́ tán ni mo ń sọ fún ọ.

Wotwɛn wo na ne w’agya, sɛ wobɛyɛ adeɛ ma wo a, w’anim agu aseɛ awie na mereka akyerɛ wo.

Ṣe bí ohun tí a kò bá jìyà fún; kìí lè tọ́jọ́

Sɛɛ na adeɛ a yɛmmrɛ ansa na yɛanya no; ntumi nkyɛ.

Ohun tí a bá fara ṣiṣẹ́ fún; l’ó ń pẹ́ l’ọ́wọ́ ẹni.

Nneɛma a yɛde yɛn ho na ɛyɛ adwuma ma saa adeɛ no; ɛno na ɛkyɛ wɔ obi nsa mu.

Apá l’ará, ìgunpá niyèkan.

Basa yɛ yɔnko, batwɛ yɛ onua.

Bí Ayé bá ń fẹ́ ọ l’ónìí, bí o bá l’ówó l’ọ́wọ́ ni wọ́n máa fẹ́ ọ l’ọ́la.

Sɛ wiase pɛ wo nnɛ a, wowɔ sika na wɔbɛpɛ wo ɔkyena.

Tàbi kí o wà nípò àtàtà, Ayé á yé ọ sí tẹ̀rín tẹ̀rín.

Anaa sɛ wowɔ dibea papa, wiase de seresere na ɛbɛkamfo wo.

Jẹ́ kí o dẹni tí ń ráágó, kí o rí i bí Ayé ti ń yínmú sí ọ.

Sɛ wo dane obi a ɔdi hia, hwɛ sɛdeɛ wiase tweaa wo.

Ẹ̀kọ́ sì tún ń sọni í dọ̀gá, múra kí o kọ́ ọ dáradára.

Adesua dane na ɛdane obi nipa kɛseɛ, yere wo ho sua no yie.

Bí o sì rí ọ̀pọ̀ ènìyàn tí ń fẹ̀kọ́ ṣẹ̀rín rín; ṣọ́ra kí o má fara wé wọn.

Bí o sì rí ọ̀pọ̀ ènìyàn tí ń fẹ̀kọ́ ṣẹ̀rín rín; ṣọ́ra kí o má fara wé wọn.

Torí ìyà ń bọ̀ fọ́mọ tí kò gbọ́n; ẹkún ń bẹ fọ́mọ tí ń sá kiri.

Ɔbrɛ reba ɛde ama akwadaa a ɔnnim nyansa; anisuo wɔ hɔ de ma akwadaa a ɔtu mmirika basabasa.

Má fòwúrọ̀ ṣeré ọ̀rẹ́ mi; múra síṣẹ ọjọ́ ń lọ.

Mfa anɔpa nni agorɔ m’adamfo, yere wo ho sua adeɛ berɛ na ɛrekɔ.

                                

Ìkíni láàrin ọjọ́ àti ọdun

Ìkíni láàrin ọjọ́ àti ọdun

Àtúnyẹ̀wò Ẹ̀kọ́

1. Àsìkò tí a ń kí ni kú àárọ̀ ni

(Àárọ̀, Ìyálẹ̀ta, Ọ̀sán)

Iṣẹ̀ Ṣíṣe

Wá ápẹẹre ọ̀rọ̀ oníròó mẹ́ta tàbí mẹ́rin jáde nínú ẹ̀kọ́ yìí.

ọ̀gbẹlẹ

 

òtútù  

 

ìtura    

Ìfẹ́ sí ohun gbogbo tí Ọlọ́run dá

Ìfẹ́ sí ohun gbogbo tí Ọlọ́run dá

_________________________ 

1. Ọ̀kan lára iṣẹ́ Ọlọ́run ni ( ẹyẹ ) 

2. Iṣẹ́ ọwọ́ ènìyàn le ( bàjẹ́ )

 

 

 

Ohun ẹlẹ́mìí  Alailẹmìí

Léwu  Ailéwu

Bàjẹ́   Dára

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

Orin Ọ̣̀ṣun

Orin Ọ̀ṣun

Àní omi ò l’ápá omi gbégi

Omi ò l’ẹ́sẹ̀ omi gbénìyàn lọ o

Ìforó ayé mi omi gbé lọ

Ìforó ayé mi omi gbé lọ

Ìganá ayé mi omi gbé lọ

Ìforó ayé mi omi gbé lọ

Gbogbo abíkú ayé mi omi gbé lọ

Oore yèyé Ọ̀ṣun oo oore yèyé ìyá o

Oore yèyé Ọ̀ṣun oo oore yèyé ìyá o

Oore yèyé Ọ̀ṣun ìyá mi oore yèyé ìyá o

Àwọn àpẹẹrẹ àwọn ọ̀rọ̀ tuntun nínú gbólóhùn

Àwọn àpẹẹrẹ àwọn ọ̀rọ̀ tuntun nínú gbólóhùn

Mo se oúnjẹ nínú ìkòkò.

Mo sùn nínú ibùsùǹ.

Mo wẹ̀ nínú garawa.

Mo fi kọ́kọ́rọ́ ṣí ilẹ̀kùn.

Mo fetí sí ẹ̀rọ asọ̀rọ̀ mágbèsì.

Mo rí ọ̀pọ̀lọ́.

Mo rí àgùtàn.

Mo rí adìẹ.

Mo rí òdòdó.

Mo fẹ́ràn afárá.

Mo jẹun lórí pèpélẹ.