Orin Ọ̀ṣun Àní omi ò l’ápá omi gbégi Omi ò l’ẹ́sẹ̀ omi gbénìyàn lọ o Ìforó ayé mi omi gbé lọ Ìforó ayé mi omi gbé lọ Ìganá ayé mi omi gbé lọ Ìforó ayé mi omi gbé lọ Gbogbo abíkú ayé mi omi gbé lọ Oore yèyé Ọ̀ṣun oo oore yèyé ìyá o Oore […]