Báwo l’a ṣe ń sọ ọ́ ní Yorùbá?

10 Ẹ̀̀wàá

20 Ogún

30 Ọgbòn

40 Ogójì

50 Àádọ́ta

60 Ọgọ́ta

70 Àádọ́rin

80 Ọgọ́rin

90 Àádọ́rùnún

100 Ọgọ́rùnún

110 Àádọ́fà

120 Ọgọ́fà

130 Àádóje

140 Ogóje

150 Àádọ́jọ

160 Ọgọ́jọ

170 Àádọsànán

180 Ọgọ́sànán 

190 Àádọwàá

200 Ọgọ́wàá́-Igba