Àwọn àpẹẹrẹ àwọn ọ̀rọ̀ tuntun nínú gbólóhùn

Mo se oúnjẹ nínú ìkòkò.

Mo sùn nínú ibùsùǹ.

Mo wẹ̀ nínú garawa.

Mo fi kọ́kọ́rọ́ ṣí ilẹ̀kùn.

Mo fetí sí ẹ̀rọ asọ̀rọ̀ mágbèsì.

Mo rí ọ̀pọ̀lọ́.

Mo rí àgùtàn.

Mo rí adìẹ.

Mo rí òdòdó.

Mo fẹ́ràn afárá.

Mo jẹun lórí pèpélẹ.